Thursday, July 19, 2018

Thursday, July 19, 2018
Ah emi ni SDK oh..Se e ni Iranti ohun_ MO ranti igba kekere,ti aman Lo ki awon obi to bi obi WA. Baba baba MI je agbe ti won ni oko cocoa, obi ati orishishi ohun ogbin.Bi aba ti gbolude olojogbogboro, ni ati ma te oko leti.Oman dun gidi nitori omode egbe wa man po.Baba ati mama ma nso itan ijapa ologbon ewe, ere osupa to badale. Awon ni won komi bi won shen ka bibeli ni ede yoruba,bi via IFTTT

0 comments:

Post a Comment