Thursday, August 16, 2018

Thursday, August 16, 2018
Eku ise oh...Emi ni Stella......Olori ti de noni mofe se intro noni,toripe Olori ko mo se.......Anytime te ba read intro ,emi lo se. Ejor e ma wo me side eyes,me ron e ise! *tongue click noni* Leeni, oriki ilu Eko Lamuwa....aki gbogbo omo eko towa Nile oo, Eko onibaje ..... Eko Akete Ile OgbonEko Aromi sa legbe legbeEko aro sese majaEko akete ilu okun alagbalugbu omi,Ta lo ni elomi via IFTTT

0 comments:

Post a Comment