Oruko Oye Awon Oba Alade Ni ile Yoruba.
Aaaaargh,emo omo oooooh....Emi ni SDK lo oun ko eleyi oh....Arrrrghhhh 1. Ooni ti ilu Ile Ife 2.Olofin ti Ilu Ife 3.Adimula ti ilu Ife 4.Alaafin ti Ilu Oyo 5.Owa Adimula ti Ile Ijesa 6.Osemawe ti Ilu Ondo 7.Ebunwawe ti Ago iwoye 8.Okere ti Ilu Saki 9.Onjo ti Ilu Okeeho 10.Sabiganma ti Iganna 11.Olu ti Ilu Ilaro 12.Akire ti Ilu Ikire 13.Orimolusi ti Ilu Ijebu Igbo. 14.Ayangbunrin ti via IFTTT
Oruko oba Ile Benin
ReplyDelete