Friday, June 15, 2018

Friday, June 15, 2018
1
Awon da?Mo ni awon daaaaaaaa?Mon se intro post yi...emi ni SDK oh... Eese me lo ko gbo gbo post yi oh...heheheheheheh sho get? Iwa jẹ iṣesi eniyan kan laarin awọn olubagbe rẹ. Bi iṣesi ẹni ba dara, awọn eniyan yoo maa pe oluwarẹ ni oniwa rere. Bi iṣesi oluwarẹ ko ba si bojumu, awọn eniyan yoo maa pe e ni oniwa buburu. Awọn ti iwa wọn ba dara ni Yooba npe ni ọmọluwabi eniyan.Ohun ti via IFTTT

1 comments: