Thursday, September 27, 2018

Thursday, September 27, 2018
Ebun Edumare si gbogbo agbaye !!! Ikogosi je ilu kekere kan ni ipile Ekiti ni orile ede Nigeria,o je ilu ti o rewa ,o si dake je.Ikogosi ni a ti ri orisun omi ti o ro worowo ati eyi ti otutu ti won si pade ara won ni oju kanno.Awon eniyan kan ti le ni gbagbo wipe omi no ni agbara lati woo isan bi ejeriru,aromolegun ati bebe lo san.Sugbon gbogbo agbara lowo olorun lowa.Itan ti omi yi fi via IFTTT

0 comments:

Post a Comment