ABEOKUTA
Abeokuta ni ilu ti o tobi julo ni ipinle Ogun. Ilu yi fidikale si apa ila oorun odo Ogun. Lara awon oun ti a le ri ra loja won ni epo pupa, igi gedu, roba, isu, iresi, agbado, owu, ori ati bee be lo. Idi ti won fi n pe e ni Abeokuta ni wi pe abe ori oke Olumo ni ilu naa wa.Oju ona reluwe wa, ti o lo lati Eko si Abeokuta, o si je kilomita merindinlogorin(77). Won se oju ona reluwe via IFTTT
0 comments:
Post a Comment