Friday, August 03, 2018

Friday, August 03, 2018
Awa ti de.awon daaaaaa!!!!..heheheheheheehehe Oruko mi ni SDK,mo fe se intro ni...LMAO Yoruba bo won ni ile laawo ka too so omo loruko. Isele to ba n sele lagbo ile ti a ti bimo tabi ona ti omo ba gba waye maa n se atokun oruko ti a o soo. Bakan naa ni ibi ti a bi omo si ati asiko , ojo, esin abbl., lo maa n niise pelu oruko ti a o so omo ni ile Yoruba.ALAYE NIPA IRU AWON OMO via IFTTT

0 comments:

Post a Comment