Wednesday, August 22, 2018

Wednesday, August 22, 2018
O je ohun Pataki fun okunrin tabi obinrin lati se igbeyawo ni igba atijo. Ni igba ti a ba gbadura fun eniyan ni ile yoruba,igbeyawo wa lara re. Gbogbo eto lesese la ma menu baa. 1.IFOJUSODENigba ti odomokunrin kan ba ti balaga, awon obi re yoo ti bere si fi oju sile boya nwon a le ri omobinrin kan tin won yoo fe fun omo won.Omokunrin yi paapaa laije pe enikeni so fun un,yoo bere si se via IFTTT

0 comments:

Post a Comment