Wednesday, July 25, 2018

Wednesday, July 25, 2018
Emi ni Sitella oh......Ejor mo fe beere nkan lowo e.. Se oro yooba ooni fullstop ati comma ni?oro yi,oro Osun state ni! Osun je ilu kekere kan ni iwo-orun gunsu ile nigeria,osun ti amenu le yii je yo lati inu ilu lakan ti amosi ilu oyo ni odun 1989,oruko ti osun je,jeyo lati ara oruko odo ti oyi ka ti amosi osun jela,odo ti aso nipa re yi tan ka gbogbo ilu osun ti orirun odo na si wa via IFTTT

0 comments:

Post a Comment