Wednesday, June 20, 2018

Wednesday, June 20, 2018
Ounje Yoruba ma dun gidigan IKOKORE 1.LAFUN: LAFUN JE OUNJE TO WOPO JU LAARIN AWON ARA EGBA .ONJE OKELE NI LAFUN JE AROMORA SII NI PELU.A LE FI ORISIRISI OBE JE SUGBON OBE TI O TAYO JULO PELU RE NI OBE GBURE OLOBORO ATI ERAN TABI EJA A SI LE FII GBONMO GBE SOFUN.2.IYAN: awon Yoruba a maa so wipe iyan to wewu egusi,to de fila isapa….I-Y-A-N. a baa lowo awon baba nla wa o si je ounje via IFTTT

0 comments:

Post a Comment