Wednesday, December 20, 2017

Wednesday, December 20, 2017
Awon eyan mi...kilon sele?..emi ni Stella lon soro.... Ama rira inside the post..hahahahahhahahaha ORIKI IBEJI {EJIRE}Ẹ̀jìrẹ́ ará ìṣokún.Ẹdúnjobí,Ọmọ ẹdun tíí ṣeré orí igi,Ọ́-bẹ́-kẹ́ṣé-bẹ́-kàṣà,Ó fẹsẹ̀ méjèèjì bẹ sílé alákìísa;Ó salákìísà donígba aṣọ.Gbajúmọ̀ ọmọ tíí gbàkúnlẹ̀ ìyá,Tíí gbàdọ̀bálẹ̀ lọ́wọ́ baba tó bí í lọ́mọ.Wínrinwínrin lójú orogúnEjìwọ̀rọ̀ lojú ìyá ẹ̀.Tani o bi via IFTTT

0 comments:

Post a Comment